Yoruba Hymn APA 85 - O de, Kristi Oluwa

Yoruba Hymn APA 85 - O de, Kristi Oluwa

 Yoruba Hymn  APA 85- O de, Kristi Oluwa

APA 85

1. O de, Kristi Oluwa,

 Lat’ ibugbe Re l’ orun,

 Lat’ ite Alafia,

 O wa si aginju wa.

 

2. Alade Alafia

 De, lati ru ’ponju wa,

 O de’ lati f’ imole

 Le okun oru wa lo. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 85 - O de, Kristi Oluwa . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post