Yoruba Hymn APA 591 - Oluwa, emi sa ti gbohun Re
APA 591
1. Oluwa, emi sa ti gbohun Re,
O nso ife Re si mi:
Sugbon mo fen de l’apa igbagbo,
Kin le tubo sunmo O.
Fa mi mora, mora Oluwa,
Sib’ agbelebu t’O ku,
Fa mi mora, mora, mora, Oluwa,
Sib’ eje Re t’o niye.
2. Ya mi si mimo fun ise Tire,
Nipa ore-ofe Re:
Je ki nfi okan igbagbo w’ oke,
K’ ife mi te si Tire.
Fa mi mora, &c.
3. A! ayo mimo ti wakati kan,
Ti mo lo nib’ ite Re,
’Gba mo gbadura si O Olorun,
Ti a soro bi ore;
Fa mi mora, &c.
4. Ijinle ife mbe ti nko le mo,
Titi ngo fi koja odo;
Ayo giga ti emi ko le so,
Titi ngo fi de ’simi.
Fa mi mora, &c.Amin
Yoruba Hymn APA 591 - Oluwa, emi sa ti gbohun Re
This is Yoruba Anglican hymns, APA 591- Oluwa, emi sa ti gbohun Re. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals