Yoruba Hymn APA 589 - Wo bi awa enia Re

Yoruba Hymn APA 589 - Wo bi awa enia Re

Yoruba Hymn  APA 589 - Wo bi awa enia Re

APA 589

 1. Wo bi awa enia Re

 Ti wole l’ ese Re;

 Olorun ! kiki anu Re

 Ni igbekele wa.


2. Idajo t’o ba ni leru,

 Nfi agbara Re han;

 Sibe, anu da ’lu wa si,

 Awa si ngbadura.


3. Olorun, o se da wa si,

 Awa alaimore?

 Jo, je k’a gbo ikilo Re,

 Nigbati anu wa.


4. Iwa buburu ti po to,

 Yika ile wa yi!

 ’Bukun ile wa lo to yi!

 Wo b’ o ti buru to.


5. Oluwa, fi ore ofe

 Yi wa l’ okan pada!

 Ki a le gba oro Re gbo,

 K’ a si wa oju Re. Amin.



Yoruba Hymn  APA 589 - Wo bi awa enia Re

This is Yoruba Anglican hymns, APA 589-  Wo bi awa enia Re. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post