Yoruba Hymn APA 553 - Ji! ko orin Mose
APA 553
1. Ji! ko orin Mose
Ati t’Od’agutan;
Ji gbogbo okan at’ ahon,
Kin won yin Oluwa.
2. Korin ti iku re,
Korin ajinde Re;
Korin b’ O ti mbebe loke,
F’ ese awon t’O ru.
3. Enyin ero l’ ona,
E korin b’ e tin lo;
E yo ninu Odagutan,
Ninu Kristi Oba.
4. E fe gbo k’O wipe,
“Alabukun, e wa”
On fere pen yin lo kuro,
K’O mu Tire lo ’le.
5. Nibe l’a o korin
Iyin Re ailopin,
Orun y’o si gbe ’rin Mose,
Ati t’Od’agutan. Amin.
Yoruba Hymn APA 553 - Ji! ko orin Mose
This is Yoruba Anglican hymns, APA 553- Ji! ko orin Mose. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals