Yoruba Hymn APA 550 - E je k’a yin Olorun wa

Yoruba Hymn APA 550 - E je k’a yin Olorun wa

Yoruba Hymn  APA 550 - E je k’a yin Olorun wa

APA 550

 1. E je k’a yin Olorun wa,

 Enit’ ’O wa l’ oke orun,

 T’ O fi onje fun enia,

 Ti O si fi fun eranko.


2. O si te oju orun lo,

 O da orun on osupa;

 Ise owo Re n’ irawo,

 Iye won awa ko le ka.


3. O si da ara enia,

 O si fun won l’ emi pelu;

 O si da ni daradara,

 Bi o ti ye, bi ’ba ti wa.


4. Sugbon enia dibaje,

 Nwon si bo s’ inu buburu,

 Ere ese ni nwon si nje,

 Ni wahala ati n’ iku.


5. Sugbon je k’a yin Olorun,

 On fun wa ni Kristi Jesu;

 Lati wa awon t’o ti nu,

 Ninu ese ti nwon ti nrin. Amin.



Yoruba Hymn  APA 550 - E je k’a yin Olorun wa

This is Yoruba Anglican hymns, APA 550-  E je k’a yin Olorun wa. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post