Yoruba Hymn APA 548 - Olugbala, a tun fe f’ohun kan

Yoruba Hymn APA 548 - Olugbala, a tun fe f’ohun kan

Yoruba Hymn  APA 548 - Olugbala, a tun fe f’ohun kan

APA 548

 1. Olugbala, a tun fe f’ohun kan

 Yin oruko Re k’a to tuka lo;

 Ni ’pari ’sin, a dide lati yin:

 A o si kunle fun ibukun Re


2. F’alafia fun wa, b’a ti nre’le,

 Je k’a pari ojo yi pelu Re;

 Pa aiya wa mo, si so ete wa,

 T’a fi pe oruko Re n’ile yi.


3. F’alafia fun wa l’oru oni,

 So okunkun re d’imole fun wa;

 Ninu ewu, yo awa omo Re,

 Okun on ’mole j’okanna fun O.


4. F’alafia fun wa loj’ aiye wa,

 Re wa l’ekun, K’O sigbe wa ni ’ja:

 ’Gbat’ O ba si f’opin s’ijamu wa,

 Pew a, Baba, s’orun alafia. Amin.



Yoruba Hymn  APA 548 - Olugbala, a tun fe f’ohun kan

This is Yoruba Anglican hymns, APA 548- Olugbala, a tun fe f’ohun kan. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post