Yoruba Hymn APA 523 - Awa ti gbe o sin, niwon l’ao daro re

Yoruba Hymn APA 523 - Awa ti gbe o sin, niwon l’ao daro re

Yoruba Hymn  APA 523 - Awa ti gbe o sin, niwon l’ao daro re

APA 523

 1. Awa ti gbe o sin, niwon l’ao daro re,

 B’o tile je nin’ okunkun l’a sin o si;

 Jesu re ti la ona kanna koja,

 Fitila ife Re ni y’o ma saju re.


2. Awa ti gbe o sin, oju wa ko ri o mo,

 O ko si tun ba war in laiye yi mo;

 Sugbon Jesu ti n’ apa ife Re si o,

 Nj’ elese le ku, nitori Jesu ti ku.


3. Awa ti gbe o sin, o ti bo ago re sile,

 Boya es’ emi re kole lati lo;

 Sugbon iwo ti ji s’ imole Paradise,

 ’Wo si ti ngbo orin awon Serafu.


4. Awa ti gbe o sin, niwon l’a o daro re,

 Olorun re li Olurapada re,

 O gba o lowo wa, y’o si ji o dide,

 Iku ko n’ oro mo, ’tori Jesu ti ku. Amin.



Yoruba Hymn  APA 523 - Awa ti gbe o sin, niwon l’ao daro re

This is Yoruba Anglican hymns, APA 523- Awa ti gbe o sin, niwon l’ao daro re. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post