Yoruba Hymn APA 522 - Itanna t’o bo ’gbe l’ aso
APA 522
1. Itanna t’o bo ’gbe l’ aso,
T’o tutu yoyo be;
Gba doje ba kan, a si ku,
A subu, a sir o.
2. Apere yi ye f’ara wa,
B’or’ Olorun ti wi;
K’omode at’ agbalagba
Mo ’ra won l’eweko.
3. A! ma gbekele emi re,
Ma pe ’gba re nitire;
Yika l’a nri doje iku,
O mbe ’gberun lule.
4. Enyin t’a dasi di oni,
Laipe, emi y’o pin,
Mura k’e sig bon l’akoko,
K’ iko iku to de.
5. Koriko, b’o ku, ki ji mo;
E ku lati tun ye;
A! b’ iku lo je ’lekun nko
S’ irora ailopin!
6. Oluwa, je k’a jipe Re,
K’a kuro n’nu ese;
Gbat’ a lule bi koriko,
K’ okan way o si O. Amin.
Yoruba Hymn APA 522 - Itanna t’o bo ’gbe l’ aso
This is Yoruba Anglican hymns, APA 522- Itanna t’o bo ’gbe l’ aso. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals