Yoruba Hymn APA 503 - Ire t’ a su ni Eden
APA 503
1. Ire t’ a su ni Eden,
N’ igbeyawo ’kini
Ibukun t’a bukun won,
O wa sibe sibe.
2. Sibe titi di oni,
N’ igbeyawo Kristian,
Olorun wa larin wa,
Lati sure fun wa.
3. Ire ki nwon le ma bi,
Ki nwon k’o si ma re;
Ki nwon ni dapo mimo,
T’ enikan k’yo le tu.
4. Ba nip e, Baba, si fa
Obirin yi f’ oko;
Bi O ti fi Efa fun
Adam lojo kini.
5. Ba wa pe Immanueli,
Si so owo won po,
B’ eda meji ti papo
L’ ara ijinle Re.
6. Baw a pe, Emi Mimo,
F’ ibukun Re fun won:
Si se won ni asepe,
Gege b’ O ti ma se.
7. Fin won sabe abo Re,
K’ ibi kan ma ba won;
’Gba nwon npara ile Re,
Ma toju okan won.
8. Pelu won l’ oj’ aiye won,
At’ oko at’ aya;
Titi nwon o de odo Re,
N’ ile ayo l’ orun. Amin.
Yoruba Hymn APA 503 - Ire t’ a su ni Eden
This is Yoruba Anglican hymns, APA 503- Ire t’ a su ni Eden. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals