Yoruba Hymn APA 495 - A o pade leti odo

Yoruba Hymn APA 495 - A o pade leti odo

Yoruba Hymn  APA 495 - A o pade leti odo


APA 495

1. A o pade leti odo,

T’ ese angeli ti te;

T’ o mo gara bi kristali,

Leba ite Olorun?

A o pade leti odo,

Odo didan, odo didan na,

Pel’ awon mimo leba odo,

T’ o nsan leba ite ni.




2. Leri bebe odo na yi,

Pel’ Olusagutan wa,

A o ma rin, a o ma sin,

B’a ti ntele ’pase Re.

A o pade leti odo, &c.



3. K’ a to de odo didan na,

A o s’ eru wa kale;

Jesu, jo gba eru ese

Awon ti O de l’ade.

A o pade leti odo, &c.




4. Nje l’eba odo tutu na,

Ao r’oju Olugbala;

Emi wa ki o pinya mo,

Yio korin ogo Re.

A o pade leti odo, &c. Amin.



Yoruba Hymn  APA 495 - A o pade leti odo

This is Yoruba Anglican hymns, APA 495- A o pade leti odo . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post