Yoruba Hymn APA 494 - Enikan mbe t’ O feran wa

Yoruba Hymn APA 494 - Enikan mbe t’ O feran wa

Yoruba Hymn  APA 494 - Enikan mbe t’ O feran wa

APA 494

1. Enikan mbe t’ O feran wa,

 A! O fe wa!

 Ife Re ju ti yekan lo,

 A! O fe wa!

 Ore aiye nko wa sile,

 B’ oni dun ola le koro,

 Sugbon ore yi ko ntanni,

 A! O fe wa!


2. Iye ni fun wa b’ a ba mo,

 A! O fe wa!

 Ro b’ a ti je ni gbese to,

 A! O fe wa!

 Eje Re l’ O si fi ra wa,

 Nin’ aganju l’ O wa wa ri,

 O si mu wa wa s’ agbo Re,

 A! O fe wa!


3. Ore ododo ni Jesu,

 A! O fe wa!

 O fe lati ma bukun wa,

 A! O fe wa!

 Okan wa fe gbo ohun Re,

 Okan wa fe lati sunmo,

 On na ko si ni tan wa je,

 A! O fe wa!


4. Loko Re l’a nri ’dariji,

 A! O fe wa!

 On O le ota wa sehin,

 A! O fe wa!

 On O pese ’bukun fun wa;

 Ire l’ a O ma ri titi

 On O fi mu wa lo s’ ogo.

 A! O fe wa! Amin. 



Yoruba Hymn  APA 494 - Enikan mbe t’ O feran wa

This is Yoruba Anglican hymns, APA 494- Enikan mbe t’ O feran wa . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post