Yoruba Hymn APA 489 - Jesu, a w’ odo Re
APA 489
1. Jesu, a w’ odo Re,
L’ ojo Re mimo yi;
To wa wa b’ awa ti pejo,
Si ko wa fun ’ra Re.
2. Dari ese ji wa,
Fun wa l’ Emi Mimo;
Ko wa k’ ihin je ibere
Aiye ti ko l’ opin.
3. F’ ife kun aiya wa,
Gba ’se oluko wa;
K’ awa at’ awon le pade
Niwaju Re loke. Amin.
Yoruba Hymn APA 489 - Jesu, a w’ odo Re
This is Yoruba Anglican hymns, APA 489- Jesu, a w’ odo Re . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals