Yoruba Hymn APA 486 - Oj’ oni lo
APA 486
1. Oj’ oni lo,
Jesu Baba,
Boju Re w’ emi omo Re.
2. ’Wo Imole,
Se ’toju mi;
Tan imole Re yi mi ka.
3. Olugbala,
Nko ni beru,
Nitori O wa lodo mi.
4. Nigba gbogbo
Ni oju Re
Nso mi, gbat’ enikan ko si.
5. Nigba gbogbo
Ni eti Re
Nso mi, gbat’ enikan ko si.
6. Nigba gbogbo
Ni eti Re
Nsi si adura omode.
7. Nitorina
Laisi foya,
Mo sun, mo si simi le O.
8. Baba, Omo,
Emi Mimo
Ni iyin ye l’ orun l’ aiye. Amin.
Yoruba Hymn APA 486 - Oj’ oni lo
This is Yoruba Anglican hymns, APA 486- Oj’ oni lo . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals