Yoruba Hymn APA 485 - Nihin l’ awa nje ’rora

Yoruba Hymn APA 485 - Nihin l’ awa nje ’rora

Yoruba Hymn  APA 485 - Nihin l’ awa nje ’rora

APA 485

 1. Nihin l’ awa nje ’rora,

 Nihin ni a ma pinya;

 L’ orun, ko si ’pinya.

 A! bi o ti dun to!

 Dun to, dun to, dun to!

 A! bi o ti dun to!

 ’Gba t’ a ki o pinya mo!


2. Awon t’ o feran Jesu,

 Nwon o lo s’ oke orun,

 Lo b’ awon t’ o ti lo,

 A! bi o ti dun to! &c.


3. Omode y’o wa nibe,

 T’ o wa Olorun l’ aiye;

 Ni gbogbo ’le eko;

 A! bi o ti dun to! &c.

 

4. Oluko, baba, iya,

 Nwon o pade nibe na;

 Nwon ki o pinya mo.

 A! bi o ti dun to! &c.


5. Bi a o ti yo po to!

 ’Gba t’ a ba r’ Olugbala,

 Ni ori ite Re!

 A! bi o ti dun to! &c.


6. Nibe l’ao korin ayo;

 Titi aiye ailopin,

 L’ a o ma yin Jesu

 A! bi o ti dun to!

 Dun to, dun to, dun to!

 A! bi o ti dun to!

 ’Gbat’ a ki o pinya mo!. Amin.



Yoruba Hymn  APA 485 - Nihin l’ awa nje ’rora

This is Yoruba Anglican hymns, APA 485- Nihin l’ awa nje ’rora. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post