Yoruba Hymn APA 483 - Olorun, orin eniti
APA 483
1. Olorun, orin eniti
Awon Angeli nko;
Wo ’le lati bujoko Re!
Ko wa, k’ a beru Re!
2. Oro mimo Re l’ a fe ko,
Lat’ igba ewe wa;
K’ a ko t’ Olugbala t’ ise
Ona, Iye, Oto.
3. Jesu, ogo at’ ore Re,
L’ a nso nisisiyi;
Se bujoko Re s’ okan wa,
Si je k’ a beru Re. Amin.
Yoruba Hymn APA 483 - Olorun, orin eniti
This is Yoruba Anglican hymns, APA 483- Olorun, orin eniti. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals