Yoruba Hymn APA 482 - Omode, e sunm’ Olorun

Yoruba Hymn APA 482 - Omode, e sunm’ Olorun

Yoruba Hymn  APA 482 - Omode, e sunm’ Olorun

APA 482

 1. Omode, e sunm’ Olorun,

 Pelu irele at’ eru;

 Ki ekun gbogbo wole fun

 Olugbala at’ Ore wa.


2. Oluwa, je k’ anu Re nla,

 Mu wa kun fun ope si O;

 Ati b’ a ti nrin lo l’ aiye,

 K’ a ma ri opo anu gba.


3. Oluwa! m’ ero buburu,

 Jinna rere si okan wa;

 L’ ojojumo fun wa l’ ogbon,

 Lati yan ona toro ni.


4. Igba aisan, at’ ilera

 Igba aini tabi oro;

 Ati l’ akoko iku wa,

 Fi agbara Tire gba wa. Amin.



Yoruba Hymn  APA 482 - Omode, e sunm’ Olorun

This is Yoruba Anglican hymns, APA 482- Omode, e sunm’ Olorun . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post