Yoruba Hymn APA 479 - Yika or’ ite Olorun

Yoruba Hymn APA 479 - Yika or’ ite Olorun

Yoruba Hymn  APA 479 - Yika or’ ite Olorun

APA 479

 1. Yika or’ ite Olorun, 

 Egberun ewe wa;

 Ewe t’ a dari ese ji,

 Awon egbe mimo:

 Nkorin Ogo, ogo, ogo.


2. Wo! olukuluku won wo

 Aso ala mimo;

 Ninu imole ailopin,

 At’ ayo ti ki sa,

 Nkorin Ogo, ogo, ogo.


3. Kil’ o mu won de aiye na,

 Orun t’ o se mimo,

 Nib’ alafia at’ ayo,

 Bi nwon ti se de ’be?

 Nkorin Ogo, ogo, ogo.


4. Nitori Jesu ta ’je Re,

 Lati k’ ese won lo;

 A ri won ninu eje na,

 Nwon di mimo laulau;

 Nkorin Ogo, ogo, ogo.


5. L’ aiye nwon wa Olugbala,

 Nwon fe oruko Re;

 Nisisiyi nwon r’ oju Re,

 Nwon wa niwaju Re;

 Nkorin Ogo, ogo, ogo.


6. Orisun na ha nsan loni?

 Jesu, mu wa de ’be;

 K’a le ri awon mimo na,

 K’a sib a won yin O,

 Nkorin Ogo, ogo, ogo. Amin.



Yoruba Hymn  APA 479 - Yika or’ ite Olorun

This is Yoruba Anglican hymns, APA 479- Yika or’ ite Olorun . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post