Yoruba Hymn APA 464 - Mo fe ki ndabi Jesu
APA 464
1. Mo fe ki ndabi Jesu,
Ninu iwa pele;
Ko s’ enit’ o gboro ’binu
Lenu Re lekan ri.
2. Mo fe ki ndabi Jesu,
L’ adura ’gbagbogbo;
Lori oke ni On nikan
Lo pade Baba Re.
3. Mo fe ki ndabi Jesu,
Emi ko ri ka pe
Bi nwon ti korira Re to,
O s’ enikan n’ ibi.
4. Mo fe ki ndabi Jesu,
Ninu ise rere;
K’a le wi nipa temi pe,
“O se ’won t’o le se.”
5. Mo fe ki ndabi Jesu,
T’o f’iyonu wipe,
“Je k’omode wa sodo Mi,”
Mo fe je ipe Re.
6. Sugbon nko dabi Jesu,
O si han gbangba be;
Jesu fun mi l’ore-ofe
Se mi ki ndabi Re. Amin.
Yoruba Hymn APA 464 - Mo fe ki ndabi Jesu
This is Yoruba Anglican hymns, APA 464- Mo fe ki ndabi Jesu . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals