Yoruba Hymn APA 451 - Wo b’ Olusagutan Israel

Yoruba Hymn APA 451 - Wo b’ Olusagutan Israel

 Yoruba Hymn  APA 451 - Wo b’ Olusagutan Israel

APA 452

1. Wo b’ Olusagutan Israel

 Ti fi ayo duro;

 Lati gb’ awon Od’ agutan,

 K’o si ko won mora.


2. On si wi pe, “Je ki nwon wa,”

 “E mase kegan won;”

 Lati sure fun iru won,

 L’Oba Angel se wa.


3. Pelu ope l’ a gbe won wa,

 A jowo won fun O;

 A yo: bi a ti je Tire,

 K’ omo wa je Tire.


4. E ma yo: odo agutan,

 K’e ma saferi Re;

 Pelu ayo ni k’ e sunmo,

 K’o le sure fun nyin.


5. Bi a ba fi won s’aiye lo,

 ’Wo to Baba fun won;

 Bi nwon si ku ni owo wa,

 Tu wa ninu, Jesu. Amin.



Yoruba Hymn  APA 451 - Wo b’ Olusagutan Israel

This is Yoruba Anglican hymns, APA 451- Wo b’ Olusagutan Israel. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals


Post a Comment (0)
Previous Post Next Post