Yoruba Hymn APA 447 - Duro, omo ogun
APA 447
1. Duro, omo ogun,
F’ enu re so f’ aiye;
Si jeje pe ofo l’ aiye,
Nitori Jesu re.
2. Dide k’ a baptis’ re,
K’ o we ese re nu,
Wa b’ Olorun da majemu,
So ’gbagbo re loni.
3. Tire ni Oluwa,
At’ ijoba orun;
Sa gb’ ami yi siwaju re,
Ami Oluwa re.
4. ’Wo k’ ise t’ ara re,
Bikose ti Kristi;
A ko oruko re po mo
Awon mimo gbani.
5. Ni hamora Jesu,
Kojuja si Esu;
B’ o ti wu k’ ogun na le to,
Iwo ni o segun.
6. Ade didara ni,
Orin na, didun ni,
Orin na, didun ni,
’Gba t’ a ba ko ikogun jo
S’ ese Olugbala. Amin.
Yoruba Hymn APA 447 - Duro, omo ogun
This is Yoruba Anglican hymns, APA 447- Duro, omo ogun. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals