Yoruba Hymn APA 443 - Sumohin, k’o gba Ara Oluwa

Yoruba Hymn APA 443 - Sumohin, k’o gba Ara Oluwa

Yoruba Hymn  APA 443 - Sumohin, k’o gba Ara Oluwa

APA 443

 1. Sumohin, k’o gba Ara Oluwa,

 K’o mu Eje mimo t’ a ta fun o.


2. Ara at’ eje na l’o gba o la,

 N’ itura okan, f’ ope f’ Olorun.


3. Elebun igbala, Omo Baba,

 Agbelebu Re fun wa n’ isegun.


4. A fi On rubo fun tagba tewe,

 On tikare l’ Ebo, On l’ Alufa.


5. Gbogb’ ebo awon Ju laiye ‘gbani

 J’ apere tin so t’ Ebo yanu yi.


6. On l’ Oludande, On ni Imole,

 O nf’ Emi ran awon Tire lowo.


7. Nje, e f’okan igbagbo sunmo ‘hin,

 Ki e si gba eri igbala yi.


8. On l’o nsakoso enia Re laiye,

 On l’ o nf’ iye ainipekun fun wa


9. O nf’ onje orun f’awon t’ebi npa,

 Omi iye fun okan npongbe


10. Onidajo wa, Olugbala wa,

 Pelu wa ni ase ife Re yi. Amin.



Yoruba Hymn  APA 443 - Sumohin, k’o gba Ara Oluwa

This is Yoruba Anglican hymns, APA 443- Sumohin, k’o gba Ara Oluwa. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals


Post a Comment (0)
Previous Post Next Post