Yoruba Hymn APA 442 - Oluwa, mo mba O pade nihin

Yoruba Hymn APA 442 - Oluwa, mo mba O pade nihin

 Yoruba Hymn  APA 442 - Oluwa, mo mba O pade nihin

APA 442

1. Oluwa, mo mba O pade nihin,

 Igbagbo mu mi wo ohun orun;

 Ngo fi agbara ro mo ore Re,

 Ngo si fi ara are mi ti O.


2. Emi ‘o je akara Olorun

 Emi o mu wain orun pelu Re;

 Nihin, ngo so eru aiye kale,

 Nihin, ngo gba idariji ese


3. Emi ko ni ‘ranwo mi lehin Re,

 Apa Re l’o to lati fara ti;

 O to wayi, Oluwa mi, o to,

 Agbara mi mbe ninu ipa Re.


4. Temi ni ese, Tire l’ododo,

 Temi l’ebi, Tire l’eje ‘wenu;

 Ewu, abo, aon alafia mi

 L’ Eje at’ ododo Re, Oluwa.


5. Gbat’ a ba dide t’ a si palemo,

 T’a ko akara ati wain kuro;

 Sibe Iwo wa nihin, Oluwa,

 Lati je Orun ati Asa mi.


6. Bi ase yi tin de ti o sin lo,

 O nran wa leti ase nla torun;

 O nfi ayo didun ase nah an,

 Ase ayo yawo Od-Agutan. Amin.



Yoruba Hymn  APA 442 - Oluwa, mo mba O pade nihin

This is Yoruba Anglican hymns, APA 442- Oluwa, mo mba O pade nihin. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals


Post a Comment (0)
Previous Post Next Post