Yoruba Hymn APA 428 - Ohun t’a fi fun O

Yoruba Hymn APA 428 - Ohun t’a fi fun O

Yoruba Hymn  APA 428 - Ohun t’a fi fun O

APA 428

 1. Ohun t’a fi fun O,

 Tire ni Oluwa:

 Gbogbo ohun ti a si ni,

 Owo Re l’o ti wa.


2. Je k’ a gba ebun Re,

 Bi iriju rere:

 Bi O si ti mbukun wa to,

 Be l’ a o fi fun O.


3. Opo ni ise nse,

 Ti nwon ko r’ onje je;

 Opo l’ o si ti sako lo,

 Kuro l’ agbo Jesu.


4. K’ a ma tu ni ninu,

 K’ a ma re ni l’ ekun,

 K’ a ma bo alainibaba,

 N’ ise t’ a ba ma se.


5. K’ a tu onde sile,

 K’ a f’ ona iye han,

 K’ a ko ni l’ ona Olorun

 B’ iwa Kristi l’ o ri.


6. A gba oro Re gbo,

 Busi igbagbo wa;

 Ohun t’ a se fun eni Re,

 Jesu, a se fun O. Amin.



Yoruba Hymn  APA 428 - Ohun t’a fi fun O

This is Yoruba Anglican hymns, APA 428- Ohun t’a fi fun O . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post