Yoruba Hymn APA 419 - Oba awon eni mimo

Yoruba Hymn APA 419 - Oba awon eni mimo

 Yoruba Hymn  APA 419 - Oba awon eni mimo

APA 419

1. Oba awon eni mimo,

 T’o mo ’ye awon ’rawo;

 Opo enit’ eda gbagbe

 Wa yika ite Re lai;


2. ’Mole ti kuku aiye bo,

 Ntan ’mole roro loke,

 Nwon je om’-alade lorun,

 Eda gbagbe won laiye.


3. Lala at’ iya won fun O,

 Eda ko rohin re mo;

 Iwa rere won farasin,

 Oluwa nikan l’o mo.


4. Nwon farasin fun wa, sugbon

 A ko won s’ iwe iye:

 Igbagbo, adura, suru,

 Lala on ’jakadi won.


5. Nwon mo isura Re lohun;

 Ka wa mo won, Oluwa,

 Nigbat’ O ba nsiro oso,

 Ti mbe lara ade Re. Amin.



 Yoruba Hymn  APA 419 - Oba awon eni mimo

This is Yoruba Anglican hymns, APA 419- Oba awon eni mimo. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post