Yoruba Hymn APA 393 - Wa, ma sise

Yoruba Hymn APA 393 - Wa, ma sise

Yoruba Hymn  APA 393 - Wa, ma sise

APA 393

 1. Wa, ma sise

 Tani gbodo s’ ole ninu oko,

 ‘Gbati gbogbo enia nkore jo?

 Kaluku ni Baba pase fun pe,

 “Sise loni.”


2. Wa, ma sise.

 Gba ‘pe giga ti angeli ko ni –

 Mu ‘hinrere to t’agba t’ewe lo:

 “Ra ‘gba pada;” wawa l’akoko nlo.

 Ile su tan.


3. Wa, ma sise.

 Oko po, alagbase ko si to,

 A n’ibi titun gba, a ni ‘po ro;

 Ohun ona jijin, at’ itosi,

 Nkigbe pe, “wa.”


4. Wa, ma sise.

 Le ‘yemeji on aigbagbo jinna,

 Ko s’alailera ti ko le se nkan:

 Ailera l’Olorun ama lo ju

 Fun ‘se nla Re.


5. Wa, ma sise.

 ‘Simi ko si, nigbat’ ise osan,

 Titi orun yio fi wo l’ ale,

 Ti awa o si gbo ohun ni pe,

 “O seun, omo.”


6. Wa, ma sise.

 Lala na dun, ere re si daju.

 ‘Bukun f’ awon t’ o f’ ori ti d’ opin:

 Ayo won, ‘smimi won, y’o ti po to,

 Lod’ Oluwa! Amin..



Yoruba Hymn  APA 393 - Wa, ma sise

This is Yoruba Anglican hymns, APA 393- Wa, ma sise . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post