Yoruba Hymn APA 389 - Okan are, ile kan mbe

Yoruba Hymn APA 389 - Okan are, ile kan mbe

 Yoruba Hymn  APA 389 - Okan are, ile kan mbe

APA 389

1. Okan are, ile kan mbe,

 L’ona jinjin s’ aiye ise;

 Ile t’ ayida ko le de,

 Tani ko fe simi nibe?

 Duro ….. roju duro, mase kun!

 Duro, duro, sa roju, mase kun!


2. Bi wahala bo o mole,

 B’ ipin re laiye ba buru,

 W’ oke s’ ile ibukun na;

 Sa roju duro, mase kun!

 Duro, &c.

 

3. Bi egun ba wa lona re,

 Ranti ori t’a f’ egun de;

 B’ ibanuje bo okan re,

 O ti ri be f’ Olugbala.

 Duro, &c.


4. Ma sise lo, mase ro pe,

 A ko gb’ adura edun re;

 Ojo isimi mbo Kankan:

 Sa roju duro, mase kun!

 Duro ….. roju duro, mase kun!

 Duro, duro, sa roju, mase kun! Amin.



Yoruba Hymn  APA 389 - Okan are, ile kan mbe

This is Yoruba Anglican hymns, APA 389-Okan are, ile kan mbe   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post