Yoruba Hymn APA 388 - Yo awon ti nsegbe, sajo eni nku

Yoruba Hymn APA 388 - Yo awon ti nsegbe, sajo eni nku

Yoruba Hymn  APA 388 - Yo awon ti nsegbe, sajo eni nku

APA 388

 1. Yo awon ti nsegbe, sajo eni nku,

 F’anu ja won kuro ninu ese,

 Ke f’awon ti nsina, gb’ eni subu ro,

 So fun won pe, Jesu le gba won la.

 Yo awon ti nsegbe, sajo eni nku,

 Alanu ni Jesu, yio gbala.

 

2. Bi nwon o tile gan, sibe O nduro

 Lati gb’ omo t’o ronupiwada;

 Sa f’ itara ro won, si ro won jeje.

 On o dariji, bi nwon je gbagbo.

 Yo awon ti nsegbe, &c.


3. Yo awon ti nsegbe, - ise tire ni;

 Oluwa yio f’agbara fun O;

 Fi suru ro won pada s’ona toro;

 So f’ asako p’ Olugbala ti ku.

 Yo awon ti nsegbe, sajo eni nku,

 Alanu ni Jesu, yio gbala. Amin.



Yoruba Hymn  APA 388 - Yo awon ti nsegbe, sajo eni nku

This is Yoruba Anglican hymns, APA 388- Yo awon ti nsegbe, sajo eni nku . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post