Yoruba Hymn APA 387 - Ao sise! ao sise! om-Olorun ni wa
APA 387
1. Ao sise! ao sise! om-Olorun ni wa,
Je k’a tele ipa ti Oluwa wa to;
K’a f’ imoran Re so agbara wa d’otun,
K’a fi gbogbo okun wa sise t’a o se,
Foriti! foriti
Ma reti, ma sona,
Titi Oluwa o fi de.
2. Ao sise! ao sise! bo awon t’ebi npa,
Ko awon alare lo s’ orison iye!
Ninu agbelebu l’awa o ma sogo,
Gbati a ba nkede pe, “Ofe n’ Igbala.”
Foriti, &c.
3. Ao sise! ao sise! l’ agbara Oluwa,
Ijoba okunkun at’ iro yio fo,
A o sig be oruko Jehofa leke,
N’nu orin iyin w ape, “Ofe n’ Igbala.”
Foriti, &c.
4. Ao sise! ao sise! l’ agbara Oluwa,
Agbada at’ ade y’o si je ere wa;
’Gbat’ ilea won oloto ba di tiwa,
Gbogbo wa o jo ho pe, “Ofe n’ Igbala.”
Foriti! foriti!
Ma reti, ma sona,
Titi Oluwa o fi de. Amin.
Yoruba Hymn APA 387 - Ao sise! ao sise! om-Olorun ni wa
This is Yoruba Anglican hymns, APA 387- Ao sise! ao sise! om-Olorun ni wa . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals