Yoruba Hymn APA 380 - Baba mi, ‘gba mba / nsako lo
APA 380
1. Baba mi, ‘gba mba / nsako lo
Kuro l’ ona Re / l’ aiye yi;
Ko mi kin le wi / bayi pe,
Se ‘fe Tire.
2. B’ ipin mi l’ aiye / ba buru,
Ko mi ki ngba, ki / nmase kun!
Ki ngbadura t’ o ko / mi, wipe,
Se ‘fe Tire.
3. B’ o ku emi ni/kansoso,
Ti ara on o/re ko si;
Ni’ teriba ngo / ma wipe,
Se ‘fe Tire.
4. B’ o fe gba ohun / owo mi,
Ohun t’ o se o/won fun mi;
Ngo fi fun O, se / Tire ni?
Se ‘fe Tire.
5. Sa fi Emi Re / tu mi n’nu,
Ki On k’ o si ma / ba mi gbe;
Eyi t’ o ku, o / d’ owo Re.
Se ‘fe Tire.
6. Tun ‘fe mi se lo/jojumo
K’ O si mu ohun / na kuro,
Ti ko je k’ emi / le wipe,
Se ‘fe Tire.
7. ‘Gbat’ emi mi ba / pin l’ aiye,
N’ ilu t’ o dara / ju aiye,
L’ emi o ma korin / na titi.
Se ‘fe Tire. Amin.
Yoruba Hymn APA 380 - Baba mi, ‘gba mba / nsako lo
This is Yoruba Anglican hymns, APA 380- Baba mi, ‘gba mba / nsako lo . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals