Yoruba Hymn APA 295 - Baba orun, nin’ oro Re

Yoruba Hymn APA 295 - Baba orun, nin’ oro Re

Yoruba Hymn  APA 295 - Baba orun, nin’ oro Re

APA 295

 1. Baba orun, nin’ oro Re

 Ni ogo orun ntan;

 Titi lai l’ a o ma yin O

 Fun Bibeli mimo.


2. Opo ’tunu wa ninu re,

 Fun okan alare;

 Gbogbo okan ti ongbe ngbe,

 Nri omi iye mu.


3. Ninu re l’ Alafia wa,

 Ti Jesu fi fun wa;

 Iye ainipekun si wa

 N’nu re fun wa gbogbo.


4. Iba le ma je ayo mi,

 Lati ma ka titi,

 Kim ma ri ogbon titun ko,

 N’nu re lojojumo.


5. Oluwa Oluko orun,

 Mase jina si mi;

 Ko mi lati fe oro Re,

 Ki nri Jesu nibe. Amin.



Yoruba Hymn  APA 295 - Baba orun, nin’ oro Re

This is Yoruba Anglican hymns, APA 295- Baba orun, nin’ oro Re . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post