Yoruba Hymn APA 294 - Iwe kan wa ti kika re

Yoruba Hymn APA 294 - Iwe kan wa ti kika re

Yoruba Hymn  APA 294 - Iwe kan wa ti kika re

APA 294

 1. Iwe kan wa ti kika re,

 Ko soro fun enia,

 Ogbon ti awon t’o ka nfe,

 Ni okan ti o mo.


2. Ise gbogbo t’ Olorun se.

 L’ oke, n’ ile; n’nu wa;

 Nwon j’ okan ninu iwe na,

 Lati f’ Olorun han.


3. Imole osupa l’ oke,

 Lat’ odo orun ni:

 Be l’ ogo Ijo Olorun,

 T’ odo Olorun wa.


4. Iwo ti O je ki a ri,

 Ohun t’ o dara yi:

 Fun wa l’ okan lati wa O,

 K’a ri O nibi gbogbo. Amin.



Yoruba Hymn  APA 294 - Iwe kan wa ti kika re

This is Yoruba Anglican hymns, APA 294- Iwe kan wa ti kika re   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post