Yoruba Hymn APA 288 - Mo f’ iyin ailopin

Yoruba Hymn APA 288 - Mo f’ iyin ailopin

 Yoruba Hymn  APA 288 - Mo f’ iyin ailopin

APA 288

1. Mo f’ iyin ailopin

 Fun Olorun Baba,

 Fun ore aiye mi,

 At’ ireti t’ orun.

 O ran Omo Re ayanfe,

 Lati ku fun ese aiye.


2. Mo f’ iyin ailopin

 Fun Olorun Omo;

 T’ O f’ eje Re we wa,

 Kuro ninu egbe:

 Nisisiyi O wa l’ Oba,

 O nri eso irora Re.


3. Mo f’ iyin ailopin

 Fun Olorun Emi:

 Eni f’ agbara Re,

 So elese d’ aye.

 O pari ise igbala,

 O si fi ayo kun okan.


4. Mo f’ ola ailopin

 Fun Olodumare,

 ’Wo Ologo meta,

 Sugbon okansoso;

 B’ O ti ju imo wa lo ni,

 A o ma f’ igbagbo yin O. Amin.



Yoruba Hymn  APA 288 - Mo f’ iyin ailopin

This is Yoruba Anglican hymns, APA 288-   Mo f’ iyin ailopin  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post