Yoruba Hymn APA 267 - Emi Eleda, nipa Re

Yoruba Hymn APA 267 - Emi Eleda, nipa Re

 Yoruba Hymn  APA 267 - Emi Eleda, nipa Re

APA 267

1. Emi Eleda, nipa Re

 L’a f’ipile aiye sole,

 Masai be gbogbo okan wo,

 Fi ayo Re si okan wa;

 Yo wa nin’ese at’ egbe,

 K’ o fi wa se ibugbe Re.


2. Orisun imole ni O,

 Ti Baba ti se ileri;

 Iwo Ina mimo orun,

 Fi ’fe orun kun okan wa;

 Jo tu ororo mimo Re

 Sori wa bi a ti nkorin.


3. Da opo ore-ofe Re,

 Lat’ orun sori gbogbo wa;

 Je k’a gba otito Re gbo,

 K’a si ma sa ro l’okan wa;

 F’ ara Re han wa k’ a le ri

 Baba at’Omo ninu Re.


4. K’a fi ola ati iyin,

 Fun Baba Olodumare;

 K’a yin oko Jesu logo,

 Enit’ o ku lati gba wa;

 Iyin bakanna ni fun O,

 Parakliti Aiyeraiye. Amin.



Yoruba Hymn  APA 267 - Emi Eleda, nipa Re

This is Yoruba Anglican hymns, APA 267-  Emi Eleda, nipa Re    . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post