Yoruba Hymn APA 254 - Lehin aiye buburu yi

Yoruba Hymn APA 254 - Lehin aiye buburu yi

Yoruba Hymn  APA 254 - Lehin aiye buburu yi

APA 254

 1. Lehin aiye buburu yi,

 Aiye ekun on osi yi,

 Ibi rere kan wa;

 Ayipada ko si nibe,

 Ko s’ oru, a f’ osan titi,

 Wi mi, ’wo o wa nibe?


2. ’Lekun ogo re ti m’ ese,

 Ohun eri ko le wo ’be,

 Lati b’ ewa re je;

 L’ ebute daradara ni,

 A ko ni gburo egun mo.

 Wi mi, ’wo o wa nibe?


3. Tan’ y’o de ’be? Onirele,

 T’ o f’ iberu sin Oluwa,

 T’ nwon ko nani aiye:

 Awon t’ a f’ Emi mimo to,

 Awon t’ o nrin lona toro,

 Awon ni o wa nibe. Amin.


Yoruba Hymn  APA 254 - Lehin aiye buburu yi

Lehin aiye buburu yi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 254- Lehin aiye buburu yi     . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post