Yoruba Hymn APA 246 - E gbo iro orin ayo orun

Yoruba Hymn APA 246 - E gbo iro orin ayo orun

 Yoruba Hymn  APA 246 -  E gbo iro orin ayo orun

APA 246

1. E gbo iro orin ayo orun,

 Orin ayo ti isegun Jesu;

 Gbogbo ota l’ o teri won ba fun,

 Ese, iku, isa-oku pelu.


2. O se tan lati lo gba ijoba,

 Fun Baba, Olorun ohun gbogbo;

 O se tan lati lo gba iyin nla,

 T’ o ye Olori-ogun ’gbala wa.


3. Ohun ikanu ni lilo Re, fun

 Awon ayanfe omo-ehin Re.

 E ma se konnu l’ oro itunu,

 “Emi nlo pese aye nyin sile.”


4. Orun gba lo kuro lehin eyi,

 Awosanma se Olugbala mo;

 Awon Ogun-orun ho fun ayo,

 Fun bibo Kristi Oluwa ogo.


5. E mase ba inu nyin je rara,

 Jesu, ireti wa, yio tun wa;

 Yio wa mu awon enia Re lo,

 Sibiti nwon o bag be titilai. Amin.


Yoruba Hymn  APA 246 -  E gbo iro orin ayo orun


This is Yoruba Anglican hymns, APA 246-   E gbo iro orin ayo orun   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post