Yoruba Hymn APA 238 - Oluwa wa orun

Yoruba Hymn APA 238 - Oluwa wa orun

Yoruba Hymn  APA 238 - Oluwa wa orun

APA 238

 1. Oluwa wa orun!

 Ago re laiye yi,

 Ibugbe ife re,

 Ewa re ti po to!

 Okan mi nfa

 Lati goke

 S’ ibugbe Re,

 Olorun mi.


2. Ayo b’awon tin sin,

 Nibiti’ Olorun yan;

 Ti nwon npara ibe,

 Lati ma josin won;

 Nwon nyin O sa;

 Ayo b’awon

 T’o fe ona

 Oke Sion.


3. Lati ipa de ‘pa

 Laiye osi wa yi;

 Titi nwon fi goke,

 Ti nwon si yo s’ orun:

 ‘Bugbe ogo!

 ‘Gbat’ Olorun

 Ba m’ ese wa

 De ibe na.


4. Olorun l’asa wa,

 Imole at’ odi;

 Owo re kun f’ ebun

 A ngba ‘bukun nibe:

 Ayo pupo

 Ni fun awon

 T’ o gbekele

 Olorun wa. Amin.



Yoruba Hymn  APA 238 - Oluwa wa orun

This is Yoruba Anglican hymns, APA 238-   Oluwa wa orun  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post