Yoruba Hymn APA 215 - Isimi awon mimo

Yoruba Hymn APA 215 - Isimi awon mimo

Yoruba Hymn  APA 215 - Isimi awon mimo

APA 215

 1. Isimi awon mimo,

 Ojo ohun ijinle,

 Ti Eleda ti bukun,

 Apere isimi Re.

 Oluwa simi ’se Re,

 O ya ’jo na si mimo


2. Loni oku Oluwa

 Nsimi ninu iboji;

 A ti we l’aso oku,

 Lat’ori titi d’ese,

 A si fi okuta se,

 A si fi edidi di.


3. Oluwa, titi aiye,

 L’a o ma pa eyi mo,

 A o t’ilekun pinpin,

 K’ariwo ma ba wole;

 A o fi suru duro,

 Tit’ Iwo o tun pada.


4. Gbogbo awon t’o ti sun,

 Nwon o wa ba O simi;

 Nwon o bo lowo lala,

 Nwon nreti ipe ’kehin,

 T’a o di eda titun,

 T’ayo wa ki y’o l’opin.


5. Jesu yo wa nin’ ese,

 K’a ba le ba won wole,

 Ewu ati ’se y’o tan,

 A o f’ayo goke lo,

 A o ri Olorun wa,

 A o si ma sin lailai. Amin.



Yoruba Hymn  APA 215 - Isimi awon mimo

This is Yoruba Anglican hymns, APA 215-  Isimi awon mimo . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals


Post a Comment (0)
Previous Post Next Post