Yoruba Hymn APA 200 - Ogo ni fun Jesu

Yoruba Hymn APA 200 - Ogo ni fun Jesu

Yoruba Hymn  APA 200 - Ogo ni fun Jesu

APA 200

 1. Ogo ni fun Jesu

 T’o f’ irora nla

 Ta eje Re fun mi

 Lati iha Re.


2. Mo r’ iye ailopin

 Ninu eje na;

 Iyonu Re sa po,

 Ore Re ki tan.


3. Ope ni titi lai,

 F’ eje ’yebiye

 T’o ra aiye pada,

 Kuro n’nu egbe.


4. Eje Abel’ nkigbe

 Si orun f’esan;

 Sugb’ eje Jesu nke

 Fun ’dariji wa.


5. Nigbati a bu won

 Okan ese wa,

 Satan, n’ idamu re,

 F’ eru sa jade.


6. Nigbat’ aiye ba nyo,

 T’o ngbe yin Re ga,

 Awon ogun Angel

 A ma f’ayo gbe.


7. Nje, e gbohun nyin ga,

 Ki iro na dun !

 Kikan lohun goro,

 Yin Odagutan. Amin.

Yoruba Hymn  APA 200 - Ogo ni fun Jesu

This is Yoruba Anglican hymns, APA 200 - Ogo ni fun Jesu. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post