Yoruba Hymn APA 184 - Jesu, l’ara Re l’awa nwo
APA 184
1. Jesu, l’ara Re l’awa nwo
Egbegberun ogo:
Ju t’ okuta iyebiye,
T’ agbada Aaroni.
2. Nwon ko le sai ko rubo na,
Fun ese ara won:
Iwa Re pe, ko l’abawon,
Mimo si l’Eda Re.
3. Jesu Oba ogo gunwa
L’Oke Sion t’ orun:
Bi Odo-agutan t’a pa,
Bi Alufa nla wa.
4. Alagbawi lodo Baba,
Ti y’o wa titi lai;
Gb’ ejo re fun, ’wo okan mi,
Gb’ ejo re fun, ’wo okan mi,
Gb’ ore-ofe Baba. Amin.
Yoruba Hymn APA 184 - Jesu, l’ara Re l’awa nwo
This is Yoruba Anglican hymns, APA 183- Jesu, l’ara Re l’awa nwo . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals