Yoruba Hymn APA 174 - Mo k’ ese mi le Jesu
APA 174
1. Mo k’ ese mi le Jesu,
Od’ agutan mimo;
O ru gbogbo eru mi,
O so mi d’ omnira;
Mo rue bi mi to wa,
K’o we eri mi nu,
K’eje Re iyebiye,
Le so mi di funfun.
2. Mo k’aini mi le Jesu,
Tire l’ohun gbogbo;
O w’arun mi gbogbo san,
O r’emi mi pada;
Mo ko ibanuje mi,
Eru, at’ aniyan,
Le Jesu, o si gba mi,
O gba irora mi.
3. Mo gb’ okan mi le Jesu,
Okan are mi yi;
Ow’ otun Re gba mi mu,
Mo simi l’aiya Re:
Mo fe oruko Jesu,
Emmanuel, Kristi;
Bi orun didun yika,
Ni oruko Re je.
4. Mo fe ki nri bi Jesu,
T’okan Re kun fun ’fe;
Mo fe ki nri bi Jesu,
Omo Mimo Baba;
Mo fe ki mba Jesu gbe,
Larin egbe mimo,
Ki nkorin iyin titi,
Orin t’angeli nko. Amin.
Yoruba Hymn APA 174 - Mo k’ ese mi le Jesu
This is Yoruba Anglican hymns, APA 174- Mo k’ ese mi le Jesu . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.