Yoruba Hymn APA 153 - Ko to k’ awon mimo beru
APA 153
1. Ko to k’ awon mimo beru,
Ki nwon so ’reti nu:
’Gba nwon ko reti ranwo Re,
Olugbala y’o de.
2. Nigbati Abram mu obe,
Olorun ni, “Duro” ;
Agbo ti o wa lohun ni,
Y’o dipo omo na.”
3. ’Gba Jona ri sinu omi,
Ko ro lati yo mo;
Sugbon Olorun ran eja,
T’ o gbe lo s’ ebute.
4. B’ iru ipa at’ ife yi
Ti po l’ oro Re to !
Emi ba ma k’ aniyan mi,
Le Oluwa lowo !
5. E duro de iranwo Re,
B’ o tile pe, Duro,
B’ ileri na tile fale,
Sugbon ko le pe de. Amin.
This is Yoruba Anglican hymns, APA 153 - Ko to k’ awon mimo beru. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.