Yoruba Hymn APA 152 - Alaimo ni emi

Yoruba Hymn APA 152 - Alaimo ni emi

Yoruba Hymn  APA 152 - Alaimo ni emi

APA 152

 1. Alaimo ni emi

 Olorun Oluwa !

 Emi ha gbodo sunmo O,

 T’ emi t’ eru ese ?


2. Eru ese yin pa

 Okan buburu mi;

 Yio ha si ti buru to,

 L’ oju Re mimo ni !


3. Emi o ha si ku,

 Ni alainireti ?

 Mo r’ ayo ninu ike Re,

 Fun otosi b’ emi.


4. Eje ni ti o ta,

 T’ ise or’ ofe Re;

 Le w’ elese t’ o buruju,

 Le m’ okan lile ro.


5. Mo wole l’ ese Re,

 Jo k’ o dariji mi;

 Nihin l’ emi o wa, titi

 ’Wo o wipe, “Dide.” Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 152 - Alaimo ni emi  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post