Yoruba Hymn APA 134 - Lati erekusu

Yoruba Hymn APA 134 - Lati erekusu

Yoruba Hymn  APA 134 - Lati erekusu

APA 134

1. Lati erekusu

 De ikangun okun,

 K’ oba juba Jesu,

 Kin won mu ore wa.

 Ki Arab le

 Orin orun;

 K’ Afrik dapo

 Gbe ’yin Re ga.


2. Om’ alade y’o sin,

 Nwon o mu ore wa;

 Lati yin agbara

 Immanuel Oba;

 Ile jijin

 Yio josin;

 Aiye y’o gba

 Ase Re gbo. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 134 - Lati erekusu  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post