Yoruba Hymn APA 116 - Ji, apa Olorun, k’ o ji

Yoruba Hymn APA 116 - Ji, apa Olorun, k’ o ji

Yoruba Hymn  APA 116 - Ji, apa Olorun, k’ o ji

APA 116

1. Ji, apa Olorun, k’ o ji,

 Gbe ’pa Re wo, mi orile;

 Ni sisin Re, je k’ aiye ri

 Isegun ise anu Re.


2. T’ ite Re wi fun keferi,

 “ Emi Jehofah Olorun.”

 Ohun Re y’o d’ ere won ru

 Yio wo pepe won lule.


3. Ma je k’ a ta ’je sile mo,

 Ebo asan fun enia;

 Si okan gbogbo ni k’ a lo

 Eje t’ o tiha Jesu yo.


4. Olodumare, n’ apa Re

 F’ opin s’ itanje Imale:

 J’ ewon isin eke Popu,

 Da ’binu agberaga ro.


5. Ki ’gbojurere Sion de,

 K’ a m’ eya Israel wa ’le

 N’ iyanu k’ a f’oju wa ri

 Keferi, Ju, l’ agbo Jesu.


6. Olodumare, lo ’fe Re,

 L’ororuko ile gbogbo;

 Ki gbogb’ ota wole fun O

 Kin won gba Jesu l’ Oluwa. Amin. 

This is Yoruba Anglican hymns, APA 116 - Ji, apa Olorun, k’ o ji . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post