Yoruba Hymn APA 114 - Alafia fun Jesu
APA 114
1. Alafia fun Jesu
Omo nla Dafidi
Ni akoko ti a yan
N’ ijoba Re bere;
O de lati tan iya,
Lati tu igbekun,
Lati mu ese kuro,
Y’o joba laisegbe.
2. Arab, alarinkiri,
Yio wole fun u;
Alejo Etiopi,
Yio wa w’ ogo Re:
Oko okun o pade
Pelu f’ isura omi
Josin lab’ ese Re.
3. Oba yio wole fun
T’ awon ti turari;
Gbogbo orile-ede,
Yio si ma yin i.
Oko okun y’o pade,
Pelu ore isin;
Lati f’isura omi
Juba niwaju Re.
4. L’ ojojumo l’ adura
Yio ma goke lo;
Ijoba Re y’o ma po
Ijoba ailopin:
Yo’ segun gbogbo ota
Y’o joko n’ ite Re;
Ogo Re yio ma ran
Alabukun lailai. Amin.
This is Yoruba Anglican hymns, APA 114 - Alafia fun Jesu. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.