Yoruba Hymn APA 109 - Jesu, b’ ise tab’ iya ni

Yoruba Hymn APA 109 - Jesu, b’ ise tab’ iya ni

Yoruba Hymn  APA 109 -  Jesu, b’ ise tab’ iya ni

APA 109

 1. Jesu, b’ ise tab’ iya ni,

 Emi o tele O !

 Bi o ti se, l’ emi o se;

 B’ o ti wa, l’ em’ o wa.


2. Irele at’ inu tutu

 Ni a ri n’ iwa Re,

 Oluwa b’ iwa Re ti ri,

 Beni ki t’ emi ri.


3. N’ igbekele or’ ofe Re

 Ni emi o ma lo;

 Emi o to ipase Re,

 De ’bugbe Re orun. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 109 -  Jesu, b’ ise tab’ iya ni . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post