Yoruba Hymn APA 104 - Ese won ti da to
APA 104
1. Ese won ti da to !
Ti nduro ni Sion;
Awon t’o mu ’hin ’gbala wa,
Awon t’o f’ayo han.
2. Ohun won ti wo to !
Ihin na ti dun to !
“Sion, w’ Olorun Oba re”
B’o ti segun nihin.
3. Eti wa ti yo to !
Lati gboro ayo;
Woli, Oba, ti duro de,
Nwon wa, nwon ko si ri.
4. Oju wa ti yo to !
T’o ri ’mole orun;
Oba, Woli, nwon wa titi,
Nwon si ku, nwon ko ri.
5. Oluwa, f’ipa han;
Lori gbogbo aiye;
Ki gbogbo orile-ede
W’ Oba Olorun won. Amin.
This is Yoruba Anglican hymns, APA 104 - Ese won ti da to . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.