Yoruba Hymn APA 101 - Olorun wa, je k’ iyin Re
APA 101
1. Olorun wa, je k’ iyin Re
Gb’ohun gbogbo wa kan;
Owo Re yi ojo wa po,
Odun miran si de.
2. Ebo wa ngoke sodo Re,
Baba, Olore wa:
Fun anu ododun tin san
Lati odo Re wa.
3. N’nu gbogbo ayida aiye,
K’anu Re wa sibe:
B’ore Re si wa si tip o,
Beni k’iyin wa po.
4. N’nu gbogbo ayida aiye,
A nri aniyan Re;
Jowo, je k’anu Re ’kanna
Bukun odun titun.
5. B’ayo ba si wa, k’ayo na
Fa wa si odo Re;
B’iya ni, awa o korin
B’ ibukun Re pelu. Amin.
This is Yoruba Anglican hymns, APA 101 - Olorun wa, je k’ iyin Re . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.