Yoruba Hymn APA 76 - E ji enyin enia
APA 76
1. E ji enyin enia
E ma se sun titi;
A ! Imole wa nlanla
On li o yo de yi.
Orun n’ imole ara,
Jesu ni ti okan ?
Ireti awon baba
Yio ha de lasan ?
2. O de k’ ewon ese tu
O de k’ okunkun lo;
E yo, ijoba Jesu
O ni rorun pupo,
E je k’ a mu ore wa
K’ a juba Oba wa
Awon amoye mu wa
A ki o mu wa bi ?
3. Je k’ a fi okan wa fun,
K’ o te ’te Re sibe;
K’ a fi ohun gbogbo fun
K’ a si se ife Re.
E yo ! e yo ! e tun yo !
Jesu Oluwa de
F’ otosi at’ oloro,
Kristi Oluwa de. Amin.
Yoruba Hymn APA 76 - E ji enyin enia
This is Yoruba Anglican hymns, APA 76 - E ji enyin enia . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.