Yoruba Anglican Hymn APA 8- Imole oro, didun yi

Yoruba Anglican Hymn APA 8- Imole oro, didun yi

Yoruba Hymn APA 8 - Imole oro, didun yi

APA 8

 1. Imole oro, didun yi

 Ji mi nin’ orun mi;

 Baba, ife Tire nikan

 L’ o pa omo Re mo.


2. Ni gbogbo oni, mo be O,

 Ma se Oluso mi;

 Dariji mi, Jesu mimo

 Ki’ m je Tire loni.

 

3. Wa se ’bugbe Re ninu mi,

 Emi ore-ofe!

 So mi di mimo laiye yi,

 K’ emi le r’ oju Re. Amin.



This is Yoruba Anglican Hymn APA 8 - Imole oro, didun yi. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post